Àìsáyà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó máa ṣe ìdájọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,Ó sì máa yanjú ọ̀rọ̀* láàárín ọ̀pọ̀ èèyàn. Wọ́n máa fi idà wọn rọ ohun ìtúlẹ̀,Wọ́n sì máa fi ọ̀kọ̀ wọn rọ ohun ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn.+ Àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́,Wọn ò sì ní kọ́ṣẹ́ ogun mọ́.+ Àìsáyà 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+ Àìsáyà 54:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 O máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in nínú òdodo.+ Ìnilára máa jìnnà réré sí ọ,+O ò ní bẹ̀rù ohunkóhun, ohunkóhun ò sì ní já ọ láyà,Torí pé kò ní sún mọ́ ọ.+ Sekaráyà 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Èmi yóò pàgọ́ bí ẹ̀ṣọ́* fún ilé mi,+Kí ẹnì kankan má bàa gba ibẹ̀ kọjá tàbí pa dà wá;Akóniṣiṣẹ́* kankan kò ní gba ibẹ̀ kọjá mọ́,+Torí mo ti fi ojú mi rí i* báyìí.
4 Ó máa ṣe ìdájọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,Ó sì máa yanjú ọ̀rọ̀* láàárín ọ̀pọ̀ èèyàn. Wọ́n máa fi idà wọn rọ ohun ìtúlẹ̀,Wọ́n sì máa fi ọ̀kọ̀ wọn rọ ohun ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn.+ Àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́,Wọn ò sì ní kọ́ṣẹ́ ogun mọ́.+
9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+
14 O máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in nínú òdodo.+ Ìnilára máa jìnnà réré sí ọ,+O ò ní bẹ̀rù ohunkóhun, ohunkóhun ò sì ní já ọ láyà,Torí pé kò ní sún mọ́ ọ.+
8 Èmi yóò pàgọ́ bí ẹ̀ṣọ́* fún ilé mi,+Kí ẹnì kankan má bàa gba ibẹ̀ kọjá tàbí pa dà wá;Akóniṣiṣẹ́* kankan kò ní gba ibẹ̀ kọjá mọ́,+Torí mo ti fi ojú mi rí i* báyìí.