Àìsáyà 55:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ dẹ etí yín sílẹ̀, kí ẹ sì wá sọ́dọ̀ mi.+ Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ* ó sì máa wà láàyè nìṣó,Ó sì dájú pé màá bá yín dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé+Bí mo ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó jẹ́ òótọ́,* hàn sí Dáfídì.+ Jeremáyà 32:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Màá sì bá wọn dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé,+ pé mi ò ní jáwọ́ nínú ṣíṣe rere fún wọn;+ màá fi ìbẹ̀rù mi sínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa kúrò lọ́dọ̀ mi.+
3 Ẹ dẹ etí yín sílẹ̀, kí ẹ sì wá sọ́dọ̀ mi.+ Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ* ó sì máa wà láàyè nìṣó,Ó sì dájú pé màá bá yín dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé+Bí mo ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó jẹ́ òótọ́,* hàn sí Dáfídì.+
40 Màá sì bá wọn dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé,+ pé mi ò ní jáwọ́ nínú ṣíṣe rere fún wọn;+ màá fi ìbẹ̀rù mi sínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa kúrò lọ́dọ̀ mi.+