ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 58:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Jèhófà á máa darí rẹ nígbà gbogbo,

      Ó sì máa tẹ́ ọ* lọ́rùn, kódà ní ilẹ̀ gbígbẹ;+

      Ó máa mú kí egungun rẹ lágbára,

      O sì máa dà bí ọgbà tí wọ́n ń bomi rin dáadáa,+

      Bí ìsun omi, tí omi rẹ̀ kì í tán.

  • Àìsáyà 60:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 A ò ní gbúròó ìwà ipá mọ́ ní ilẹ̀ rẹ,

      A ò sì ní gbúròó ìparun àti ìwópalẹ̀ nínú àwọn ààlà rẹ.+

      O máa pe àwọn ògiri rẹ ní Ìgbàlà,+ o sì máa pe àwọn ẹnubodè rẹ ní Ìyìn.

  • Àìsáyà 62:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ẹ má ṣe jẹ́ kó sinmi rárá, títí ó fi máa fìdí Jerúsálẹ́mù múlẹ̀ gbọn-in,

      Àní, títí ó fi máa fi í ṣe ìyìn ayé.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́