-
Àwọn Onídàájọ́ 6:36, 37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Gídíónì wá sọ fún Ọlọ́run tòótọ́ pé: “Tó bá jẹ́ pé èmi lo fẹ́ lò láti gba Ísírẹ́lì sílẹ̀, bí o ṣe ṣèlérí+ gẹ́lẹ́, 37 mo máa tẹ́ ìṣùpọ̀ irun àgùntàn sílẹ̀ ní ibi ìpakà. Tí ìrì bá sẹ̀ sórí ìṣùpọ̀ irun náà nìkan, àmọ́ tí gbogbo ilẹ̀ tó yí i ká gbẹ, ìgbà yẹn ni màá mọ̀ pé èmi lo máa lò láti gba Ísírẹ́lì sílẹ̀, bí o ṣe ṣèlérí gẹ́lẹ́.”
-