ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 34:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Torí Jèhófà ní ọjọ́ ẹ̀san,+

      Ọdún ẹ̀san torí ẹjọ́ lórí Síónì.+

  • Àìsáyà 35:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ẹ sọ fún àwọn tó ń ṣàníyàn nínú ọkàn wọn pé:

      “Ẹ jẹ́ alágbára. Ẹ má bẹ̀rù.

      Ẹ wò ó! Ọlọ́run yín máa wá gbẹ̀san,

      Ọlọ́run máa wá láti fìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹni.+

      Ó máa wá gbà yín sílẹ̀.”+

  • Àìsáyà 61:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+

      Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+

      Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,

      Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,

      Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+

       2 Láti kéde ọdún ìtẹ́wọ́gbà* Jèhófà

      Àti ọjọ́ ẹ̀san Ọlọ́run wa,+

      Láti tu gbogbo àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ nínú,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́