ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 34:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 A ò ní pa á, ní òru tàbí ní ọ̀sán;

      Èéfín rẹ̀ á máa ròkè títí láé.

      Ibi ìparun ló máa jẹ́ láti ìran dé ìran;

      Kò sẹ́ni tó máa gba ibẹ̀ kọjá títí láé àti láéláé.+

  • Mátíù 25:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 “Ó máa wá sọ fún àwọn tó wà ní òsì rẹ̀ pé: ‘Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi,+ ẹ̀yin tí a ti gégùn-ún fún, ẹ lọ sínú iná àìnípẹ̀kun+ tí a ṣètò sílẹ̀ fún Èṣù àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀.+

  • Máàkù 9:47, 48
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 Tí ojú rẹ bá sì mú ọ kọsẹ̀, sọ ọ́ nù.+ Ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba Ọlọ́run ní olójú kan ju kí a jù ọ́ sínú Gẹ̀hẹ́nà*+ pẹ̀lú ojú méjèèjì, 48 níbi tí ìdin kì í ti í kú, tí a kì í sì í pa iná.+

  • 2 Tẹsalóníkà 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àwọn yìí máa fara gbá ìyà ìdájọ́ ìparun ayérayé+ láti iwájú Olúwa àti látinú ògo agbára rẹ̀,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́