2 Àwọn Ọba 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+ Hósíà 10:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ohun tí a ó ṣe sí ọ nìyí, ìwọ Bẹ́tẹ́lì,+ nítorí ìwà búburú rẹ tó bùáyà. Ní àfẹ̀mọ́jú, ó dájú pé a ó pa ọba Ísírẹ́lì.”*+
6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+
15 Ohun tí a ó ṣe sí ọ nìyí, ìwọ Bẹ́tẹ́lì,+ nítorí ìwà búburú rẹ tó bùáyà. Ní àfẹ̀mọ́jú, ó dájú pé a ó pa ọba Ísírẹ́lì.”*+