Àìsáyà 8:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wò ó! Èmi àti àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi+ dà bí àmì+ àti iṣẹ́ ìyanu ní Ísírẹ́lì látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ẹni tó ń gbé lórí Òkè Síónì. Àìsáyà 24:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Òṣùpá àrànmọ́jú máa tẹ́,Ojú sì máa ti oòrùn tó ń ràn,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti di Ọba+ ní Òkè Síónì+ àti ní Jerúsálẹ́mù,Ògo rẹ̀ ń tàn níwájú àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn rẹ̀.*+
18 Wò ó! Èmi àti àwọn ọmọ tí Jèhófà fún mi+ dà bí àmì+ àti iṣẹ́ ìyanu ní Ísírẹ́lì látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ẹni tó ń gbé lórí Òkè Síónì.
23 Òṣùpá àrànmọ́jú máa tẹ́,Ojú sì máa ti oòrùn tó ń ràn,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti di Ọba+ ní Òkè Síónì+ àti ní Jerúsálẹ́mù,Ògo rẹ̀ ń tàn níwájú àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn rẹ̀.*+