Sáàmù 97:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 97 Jèhófà ti di Ọba!+ Kí inú ayé máa dùn.+ Kí ọ̀pọ̀ erékùṣù máa yọ̀.+ Ìfihàn 11:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 wọ́n ní: “A dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè, ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ torí o ti gba agbára ńlá rẹ, o sì ti ń jọba.+
17 wọ́n ní: “A dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè, ẹni tó ti wà tipẹ́, tó sì wà báyìí,+ torí o ti gba agbára ńlá rẹ, o sì ti ń jọba.+