Àìsáyà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Íjíbítì:+ Wò ó! Jèhófà gun àwọsánmà tó ń yára kánkán, ó sì ń bọ̀ wá sí Íjíbítì. Àwọn ọlọ́run Íjíbítì tí kò ní láárí máa gbọ̀n rìrì níwájú rẹ̀,+Ọkàn Íjíbítì sì máa domi nínú rẹ̀. Jeremáyà 46:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún wòlíì Jeremáyà nípa bí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣe máa wá pa ilẹ̀ Íjíbítì rẹ́ nìyí:+
19 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Íjíbítì:+ Wò ó! Jèhófà gun àwọsánmà tó ń yára kánkán, ó sì ń bọ̀ wá sí Íjíbítì. Àwọn ọlọ́run Íjíbítì tí kò ní láárí máa gbọ̀n rìrì níwájú rẹ̀,+Ọkàn Íjíbítì sì máa domi nínú rẹ̀.
13 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún wòlíì Jeremáyà nípa bí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣe máa wá pa ilẹ̀ Íjíbítì rẹ́ nìyí:+