-
Àìsáyà 3:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Wò ó! Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,
Ó ń mú gbogbo ìtìlẹ́yìn àtàwọn ohun tí wọ́n nílò ní Jerúsálẹ́mù àti Júdà kúrò,
Gbogbo ìtìlẹ́yìn oúnjẹ àti omi,+
-
Ìdárò 4:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Àwọn tí idà pa sàn ju àwọn tí ìyàn pa,+
Àwọn tó ń kú lọ, tí ìyàn mú débi pé ìrora wọn dà bí ìgbà tí idà gúnni.
-
-
-