ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 23:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ìkéde nípa Tírè:+

      Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+

      Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀.

      A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+

  • Ìsíkíẹ́lì 26:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Màá sọ ọ́ di àpáta lásán tó ń dán àti ibi tí wọ́n ti ń sá àwọ̀n.+ Wọn ò ní tún ọ kọ́ láé, torí èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.

  • Ìsíkíẹ́lì 26:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Wọ́n á kọ orin arò*+ torí rẹ, wọ́n á sì sọ fún ọ pé:

      “Wo bí o ti ṣègbé,+ ìwọ tí àwọn tó wá láti òkun ń gbé inú rẹ̀, ìwọ ìlú tí wọ́n ń yìn;

      Ìwọ àti àwọn* tó ń gbé inú rẹ jẹ́ alágbára lórí òkun,+

      Ẹ sì ń dẹ́rù ba gbogbo àwọn tó ń gbé ayé!

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́