Léfítíkù 26:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Èmi yóò mú kí idà pa àwọn ìlú yín,+ màá sì sọ àwọn ibi mímọ́ yín di ahoro, mi ò ní gbọ́ òórùn dídùn* àwọn ẹbọ yín. Diutarónómì 29:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí náà, Jèhófà fi ìbínú àti ìrunú àti ìkannú ńlá fà wọ́n tu kúrò ní ilẹ̀ wọn,+ ó sì kó wọn lọ sí ilẹ̀ míì níbi tí wọ́n wà lónìí.’+
31 Èmi yóò mú kí idà pa àwọn ìlú yín,+ màá sì sọ àwọn ibi mímọ́ yín di ahoro, mi ò ní gbọ́ òórùn dídùn* àwọn ẹbọ yín.
28 Torí náà, Jèhófà fi ìbínú àti ìrunú àti ìkannú ńlá fà wọ́n tu kúrò ní ilẹ̀ wọn,+ ó sì kó wọn lọ sí ilẹ̀ míì níbi tí wọ́n wà lónìí.’+