ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:49, 50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 “Jèhófà máa gbé orílẹ̀-èdè kan tó wà lọ́nà jíjìn+ dìde sí ọ, láti ìkángun ayé; ó máa kì ọ́ mọ́lẹ̀ bí ẹyẹ idì+ ṣe ń ṣe, orílẹ̀-èdè tí o ò ní gbọ́+ èdè rẹ̀, 50 orílẹ̀-èdè tí ojú rẹ̀ le gan-an, tí kò ní wo ojú arúgbó, tí kò sì ní ṣojúure sí àwọn ọmọdé.+

  • Jeremáyà 5:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 “Wò ó, màá mú orílẹ̀-èdè kan láti ibi tó jìnnà wá bá yín, ẹ̀yin ilé Ísírẹ́lì,”+ ni Jèhófà wí.

      “Orílẹ̀-èdè tó ti wà tipẹ́tipẹ́ ni.

      Orílẹ̀-èdè àtijọ́ ni,

      Orílẹ̀-èdè tí ìwọ kò gbọ́ èdè rẹ̀,

      Tí ọ̀rọ̀ rẹ̀ kò lè yé ọ.+

  • 1 Kọ́ríńtì 14:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ó wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin pé: “‘Màá bá àwọn èèyàn yìí sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ ahọ́n àwọn àjèjì àti nípasẹ̀ ètè àwọn àjèjì, síbẹ̀ náà, wọn ò ní fetí sí mi,’ ni Jèhófà* wí.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́