42 Jésù sọ fún wọn pé: “Ṣé ẹ ò tíì kà á nínú Ìwé Mímọ́ rí pé, ‘Òkúta tí àwọn kọ́lékọ́lé kọ̀ sílẹ̀, òun ló wá di olórí òkúta igun ilé.*+ Ọ̀dọ̀ Jèhófà* ni èyí ti wá, ó sì jẹ́ ìyanu lójú wa’?+
17 Àmọ́ ó wò wọ́n tààràtà, ó sì sọ pé: “Kí wá ni èyí túmọ̀ sí, ohun tí a kọ pé, ‘Òkúta tí àwọn kọ́lékọ́lé kọ̀ sílẹ̀, òun ló wá di olórí òkúta igun ilé’?*+