Jeremáyà 33:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ‘Wò ó, màá mú kí ara rẹ̀ kọ́fẹ, màá sì fún un ní ìlera,+ màá mú wọn lára dá, màá sì fún wọn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà àti òtítọ́.+ Émọ́sì 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 ‘Ní ọjọ́ yẹn, màá gbé àtíbàbà* Dáfídì+ tó ti wó dìde,Màá sì tún àwọn àlàfo rẹ̀* ṣe,Màá tún àwókù rẹ̀ kọ́;Màá tún un kọ́, á sì rí bíi ti tẹ́lẹ̀,+
6 ‘Wò ó, màá mú kí ara rẹ̀ kọ́fẹ, màá sì fún un ní ìlera,+ màá mú wọn lára dá, màá sì fún wọn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà àti òtítọ́.+
11 ‘Ní ọjọ́ yẹn, màá gbé àtíbàbà* Dáfídì+ tó ti wó dìde,Màá sì tún àwọn àlàfo rẹ̀* ṣe,Màá tún àwókù rẹ̀ kọ́;Màá tún un kọ́, á sì rí bíi ti tẹ́lẹ̀,+