Àìsáyà 22:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìwọ tí rúkèrúdò kún inú rẹ,Ìwọ ìlú aláriwo, ìlú tó ń yọ̀ gidigidi. Kì í ṣe idà ni wọ́n fi pa àwọn èèyàn rẹ tí wọ́n pa,Bẹ́ẹ̀ ni wọn ò kú sójú ogun.+ Ìdárò 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ lójú ọ̀nà ń fi ọ́ ṣẹ̀sín, wọ́n sì ń pàtẹ́wọ́.+ Wọ́n ń súfèé nítorí ìyàlẹ́nu,+ wọ́n sì ń mi orí wọn sí ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù, pé: “Ṣé ìlú yìí ni wọ́n máa ń sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Ẹwà rẹ̀ pé, ó jẹ́ ayọ̀ gbogbo ayé’?”+
2 Ìwọ tí rúkèrúdò kún inú rẹ,Ìwọ ìlú aláriwo, ìlú tó ń yọ̀ gidigidi. Kì í ṣe idà ni wọ́n fi pa àwọn èèyàn rẹ tí wọ́n pa,Bẹ́ẹ̀ ni wọn ò kú sójú ogun.+
15 Gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ lójú ọ̀nà ń fi ọ́ ṣẹ̀sín, wọ́n sì ń pàtẹ́wọ́.+ Wọ́n ń súfèé nítorí ìyàlẹ́nu,+ wọ́n sì ń mi orí wọn sí ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù, pé: “Ṣé ìlú yìí ni wọ́n máa ń sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Ẹwà rẹ̀ pé, ó jẹ́ ayọ̀ gbogbo ayé’?”+