Léfítíkù 26:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Èmi yóò mú kí idà pa àwọn ìlú yín,+ màá sì sọ àwọn ibi mímọ́ yín di ahoro, mi ò ní gbọ́ òórùn dídùn* àwọn ẹbọ yín. Léfítíkù 26:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run.
31 Èmi yóò mú kí idà pa àwọn ìlú yín,+ màá sì sọ àwọn ibi mímọ́ yín di ahoro, mi ò ní gbọ́ òórùn dídùn* àwọn ẹbọ yín.
33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run.