-
Jeremáyà 44:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Ohun tí ẹ̀yin àti àwọn ìyàwó yín ti fi ẹnu yín sọ, ni ẹ fi ọwọ́ yín mú ṣẹ, torí ẹ sọ pé: “Àá rí i dájú pé a mú ẹ̀jẹ́ wa ṣẹ pé a ó rú ẹbọ sí Ọbabìnrin Ọ̀run,* a ó sì da ọrẹ ohun mímu jáde sí i.”+ Ó dájú pé ẹ̀yin obìnrin yìí máa mú ẹ̀jẹ́ yín ṣẹ, ẹ ó sì pa ẹ̀jẹ́ yín mọ́.’
-