Léfítíkù 26:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run. Jeremáyà 44:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Ẹ ti rí gbogbo àjálù tí mo mú bá Jerúsálẹ́mù+ àti gbogbo àwọn ìlú Júdà, wọ́n ti di àwókù lónìí yìí, kò sì sí ẹni tó ń gbé inú wọn.+
33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run.
2 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Ẹ ti rí gbogbo àjálù tí mo mú bá Jerúsálẹ́mù+ àti gbogbo àwọn ìlú Júdà, wọ́n ti di àwókù lónìí yìí, kò sì sí ẹni tó ń gbé inú wọn.+