Sáàmù 37:39, 40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìgbàlà àwọn olódodo ti wá;+Òun ni odi ààbò wọn ní àkókò wàhálà.+ 40 Jèhófà á ràn wọ́n lọ́wọ́, á sì gbà wọ́n sílẹ̀.+ Á gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú, á sì gbà wọ́n là,Nítorí òun ni wọ́n fi ṣe ibi ààbò.+ Jeremáyà 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbùkún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà,Ẹni tó fi Jèhófà ṣe ìgbọ́kànlé rẹ̀.+
39 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìgbàlà àwọn olódodo ti wá;+Òun ni odi ààbò wọn ní àkókò wàhálà.+ 40 Jèhófà á ràn wọ́n lọ́wọ́, á sì gbà wọ́n sílẹ̀.+ Á gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú, á sì gbà wọ́n là,Nítorí òun ni wọ́n fi ṣe ibi ààbò.+