ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 25:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+

  • Jeremáyà 25:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 lẹ́yìn náà, Fáráò ọba Íjíbítì àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àwọn ìjòyè rẹ̀ àti gbogbo èèyàn rẹ̀+

  • Jeremáyà 46:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún wòlíì Jeremáyà nípa bí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣe máa wá pa ilẹ̀ Íjíbítì rẹ́ nìyí:+

  • Ìsíkíẹ́lì 29:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Èmi yóò fún Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ yóò kó ọrọ̀ rẹ̀ lọ, yóò sì kó ọ̀pọ̀ ẹrù rẹ̀, yóò kó o bọ̀ láti ogun; ìyẹn yóò sì jẹ́ èrè fún àwọn ọmọ ogun rẹ̀.’

  • Ìsíkíẹ́lì 30:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Idà yóò dojú kọ Íjíbítì, ìbẹ̀rù á sì bo Etiópíà nígbà tí òkú bá sùn ní Íjíbítì;

      Wọ́n ti kó ọrọ̀ rẹ̀, wọ́n sì ti wó ìpìlẹ̀ rẹ̀.+

  • Ìsíkíẹ́lì 30:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ojú ọjọ́ yóò ṣókùnkùn ní Tehafínéhésì nígbà tí mo bá ṣẹ́ àwọn ọ̀pá àjàgà Íjíbítì níbẹ̀.+ Agbára tó ń mú kó gbéra ga yóò dópin,+ ìkùukùu* á bò ó, àwọn ìlú rẹ̀ yóò sì lọ sí oko ẹrú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́