-
Nọ́ńbà 21:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 O gbé, ìwọ Móábù! Ẹ máa pa run, ẹ̀yin ará Kémóṣì!+
Ó sọ àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ di ìsáǹsá, ó sì sọ àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ di ẹrú Síhónì, ọba àwọn Ámórì.
-