ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 21:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Mósè rán àwọn ọkùnrin kan lọ ṣe amí Jásérì.+ Wọ́n gba àwọn àrọko rẹ̀,* wọ́n sì lé àwọn Ámórì tí wọ́n wà níbẹ̀ kúrò.

  • Nọ́ńbà 32:34, 35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Àwọn ọmọ Gádì kọ́* Díbónì,+ Átárótì,+ Áróérì,+ 35 Atiroti-ṣófánì, Jásérì,+ Jógíbéhà,+

  • Jóṣúà 21:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+

  • Jóṣúà 21:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Hẹ́ṣíbónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Jásérì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú mẹ́rin.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́