Àìsáyà 34:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà ní idà kan; ẹ̀jẹ̀ máa bò ó. Ọ̀rá+ máa bò ó,Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọ àgbò àti ewúrẹ́ máa bò ó,Ọ̀rá kíndìnrín àwọn àgbò máa bò ó. Torí pé Jèhófà ní ẹbọ ní Bósírà,Ó máa pa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ní ilẹ̀ Édómù.+ Àìsáyà 34:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 A ò ní pa á, ní òru tàbí ní ọ̀sán;Èéfín rẹ̀ á máa ròkè títí láé. Ibi ìparun ló máa jẹ́ láti ìran dé ìran;Kò sẹ́ni tó máa gba ibẹ̀ kọjá títí láé àti láéláé.+
6 Jèhófà ní idà kan; ẹ̀jẹ̀ máa bò ó. Ọ̀rá+ máa bò ó,Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọ àgbò àti ewúrẹ́ máa bò ó,Ọ̀rá kíndìnrín àwọn àgbò máa bò ó. Torí pé Jèhófà ní ẹbọ ní Bósírà,Ó máa pa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ní ilẹ̀ Édómù.+
10 A ò ní pa á, ní òru tàbí ní ọ̀sán;Èéfín rẹ̀ á máa ròkè títí láé. Ibi ìparun ló máa jẹ́ láti ìran dé ìran;Kò sẹ́ni tó máa gba ibẹ̀ kọjá títí láé àti láéláé.+