Sáàmù 137:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+ Jeremáyà 51:56 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 56 Nítorí apanirun máa dé sórí Bábílónì;+A ó mú àwọn jagunjagun rẹ̀,+A ó ṣẹ́ ọfà* wọn sí wẹ́wẹ́,Nítorí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run ẹ̀san.+ Ó dájú pé ó máa gbẹ̀san.+
8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+
56 Nítorí apanirun máa dé sórí Bábílónì;+A ó mú àwọn jagunjagun rẹ̀,+A ó ṣẹ́ ọfà* wọn sí wẹ́wẹ́,Nítorí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run ẹ̀san.+ Ó dájú pé ó máa gbẹ̀san.+