-
Jeremáyà 51:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Àwọn orílẹ̀-èdè kò sì ní rọ́ lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ mọ́,
Ògiri Bábílónì sì máa ṣubú.+
-
-
Jeremáyà 51:52Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
52 “Torí náà, wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí,
“Tí màá yíjú sí àwọn ère gbígbẹ́ rẹ̀,
Àwọn tó fara pa yóò máa kérora ní gbogbo ilẹ̀ rẹ̀.”+
-
-
Dáníẹ́lì 5:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Wọ́n mu wáìnì, wọ́n sì yin àwọn ọlọ́run tí wọ́n fi wúrà, fàdákà, bàbà, irin, igi àti òkúta ṣe.
-