Diutarónómì 32:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Tèmi ni ẹ̀san àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀,+Ní àkókò náà tí ẹsẹ̀ wọn máa yọ̀ tẹ̀rẹ́,+Torí ọjọ́ àjálù wọn sún mọ́lé,Ohun tó sì ń dúró dè wọ́n máa tètè dé.’
35 Tèmi ni ẹ̀san àti ìyà ẹ̀ṣẹ̀,+Ní àkókò náà tí ẹsẹ̀ wọn máa yọ̀ tẹ̀rẹ́,+Torí ọjọ́ àjálù wọn sún mọ́lé,Ohun tó sì ń dúró dè wọ́n máa tètè dé.’