Àìsáyà 44:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ẹni tó ń sọ fún ibú omi pé, ‘Gbẹ,Màá sì mú kí gbogbo odò rẹ gbẹ táútáú’;+ Jeremáyà 50:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ìparun máa wà yí ká omi rẹ̀, a ó mú kó gbẹ táútáú.+ Nítorí ilẹ̀ ère gbígbẹ́ ni,+Wọ́n sì ń ṣe bíi wèrè nítorí àwọn ìran tó ń bani lẹ́rù tí wọ́n ń rí.
27 Ẹni tó ń sọ fún ibú omi pé, ‘Gbẹ,Màá sì mú kí gbogbo odò rẹ gbẹ táútáú’;+ Jeremáyà 50:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ìparun máa wà yí ká omi rẹ̀, a ó mú kó gbẹ táútáú.+ Nítorí ilẹ̀ ère gbígbẹ́ ni,+Wọ́n sì ń ṣe bíi wèrè nítorí àwọn ìran tó ń bani lẹ́rù tí wọ́n ń rí.
38 Ìparun máa wà yí ká omi rẹ̀, a ó mú kó gbẹ táútáú.+ Nítorí ilẹ̀ ère gbígbẹ́ ni,+Wọ́n sì ń ṣe bíi wèrè nítorí àwọn ìran tó ń bani lẹ́rù tí wọ́n ń rí.