-
Àìsáyà 44:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ẹni tó ń sọ fún ibú omi pé, ‘Gbẹ,
Màá sì mú kí gbogbo odò rẹ gbẹ táútáú’;+
-
Jeremáyà 51:36, 37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
Màá mú kí omi òkun rẹ̀ gbẹ, màá sì mú kí àwọn kànga rẹ̀ gbẹ.+
-
-
-