ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 50:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ẹ kígbe ogun mọ́ ọn láti ibi gbogbo.

      Ó ti juwọ́ sílẹ̀.*

      Àwọn òpó rẹ̀ ti ṣubú, àwọn ògiri rẹ̀ sì ti ya lulẹ̀,+

      Nítorí ẹ̀san Jèhófà ni.+

      Ẹ gbẹ̀san lára rẹ̀.

      Bí ó ti ṣe síni ni kí ẹ ṣe sí i gẹ́lẹ́.+

  • Jeremáyà 51:44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 Màá yí ojú mi sí Bélì+ ní Bábílónì,

      Màá sì yọ ohun tí ó ti gbé mì jáde ní ẹnu rẹ̀.+

      Àwọn orílẹ̀-èdè kò sì ní rọ́ lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ mọ́,

      Ògiri Bábílónì sì máa ṣubú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́