-
Diutarónómì 28:23, 24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ojú ọ̀run tó wà lókè orí rẹ máa di bàbà, ilẹ̀ tó sì wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ máa di irin.+ 24 Jèhófà máa sọ òjò ilẹ̀ rẹ di nǹkan lẹ́búlẹ́bú àti eruku tí á máa kù sórí rẹ láti ọ̀run títí o fi máa pa run.
-
-
Jeremáyà 3:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Torí náà ni òjò kò fi rọ̀,+
Tí kò sì sí òjò ní ìgbà ìrúwé.
-