-
Àìsáyà 66:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ẹni tó ń pa akọ màlúù dà bí ẹni tó ń ṣá èèyàn balẹ̀.+
Ẹni tó ń fi àgùntàn rúbọ dà bí ẹni tó ń ṣẹ́ ọrùn ajá.+
Ẹni tó ń mú ẹ̀bùn wá dà bí ẹni tó ń fi ẹ̀jẹ̀ ẹlẹ́dẹ̀ rúbọ!+
Ẹni tó ń mú oje igi tùràrí wá láti fi ṣe ọrẹ ìrántí+ dà bí ẹni tó ń fi ọfọ̀ súre.*+
Wọ́n ti yan ọ̀nà tiwọn,
Ohun ìríra ló sì ń múnú wọn dùn.*
-
-
Jeremáyà 7:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Ẹ lọ, kí ẹ fi odindi ẹbọ sísun yín kún àwọn ẹbọ yín yòókù, kí ẹ sì jẹ ẹran rẹ̀.+
-