Àìsáyà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Àǹfààní wo ni ọ̀pọ̀ ẹbọ yín ń ṣe mí?”+ ni Jèhófà wí. “Àwọn ẹbọ sísun yín tí ẹ fi àgbò+ ṣe àti ọ̀rá àwọn ẹran tí ẹ bọ́ dáadáa + ti sú mi,Inú mi ò dùn sí ẹ̀jẹ̀+ àwọn akọ ọmọ màlúù,+ ọ̀dọ́ àgùntàn àti ewúrẹ́.+ Jeremáyà 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Kò já mọ́ nǹkan kan lójú mi pé ẹ̀ ń mú oje igi tùràrí wá láti ṢébàÀti pòròpórò olóòórùn dídùn* láti ilẹ̀ tó jìnnà. Àwọn odindi ẹbọ sísun yín kò ní ìtẹ́wọ́gbà,Àwọn ẹbọ yín kò sì mú inú mi dùn.”+ Hósíà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n ń fi ẹran rúbọ sí mi, wọ́n sì jẹ ẹran náà,Ṣùgbọ́n inú Jèhófà kò dùn sí ẹbọ wọn.+ Ó máa rántí ẹ̀ṣẹ̀ wọn, á sì fìyà jẹ wọ́n nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Wọ́n ti yíjú* sí Íjíbítì.+ Émọ́sì 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mo kórìíra àwọn àjọyọ̀ yín, mo sì kọ̀ wọ́n,+Inú mi ò dùn sí òórùn àwọn àpéjọ ọlọ́wọ̀ yín.
11 “Àǹfààní wo ni ọ̀pọ̀ ẹbọ yín ń ṣe mí?”+ ni Jèhófà wí. “Àwọn ẹbọ sísun yín tí ẹ fi àgbò+ ṣe àti ọ̀rá àwọn ẹran tí ẹ bọ́ dáadáa + ti sú mi,Inú mi ò dùn sí ẹ̀jẹ̀+ àwọn akọ ọmọ màlúù,+ ọ̀dọ́ àgùntàn àti ewúrẹ́.+
20 “Kò já mọ́ nǹkan kan lójú mi pé ẹ̀ ń mú oje igi tùràrí wá láti ṢébàÀti pòròpórò olóòórùn dídùn* láti ilẹ̀ tó jìnnà. Àwọn odindi ẹbọ sísun yín kò ní ìtẹ́wọ́gbà,Àwọn ẹbọ yín kò sì mú inú mi dùn.”+
13 Wọ́n ń fi ẹran rúbọ sí mi, wọ́n sì jẹ ẹran náà,Ṣùgbọ́n inú Jèhófà kò dùn sí ẹbọ wọn.+ Ó máa rántí ẹ̀ṣẹ̀ wọn, á sì fìyà jẹ wọ́n nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Wọ́n ti yíjú* sí Íjíbítì.+