Jẹ́nẹ́sísì 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọmọ Jáfẹ́tì ni Gómérì,+ Mágọ́gù,+ Mádáì, Jáfánì, Túbálì,+ Méṣékì+ àti Tírásì.+ Jẹ́nẹ́sísì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ọmọ Jáfánì ni Élíṣáhì,+ Táṣíṣì,+ Kítímù+ àti Dódánímù.