Dáníẹ́lì 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Gbogbo Ísírẹ́lì ti tẹ Òfin rẹ lójú, wọ́n sì ti yà kúrò nínú rẹ̀ torí pé wọn ò ṣègbọràn sí ohùn rẹ, tí o fi da ègún àti ìbúra lé wa lórí, èyí tí wọ́n kọ sínú Òfin Mósè ìránṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́,+ torí pé a ti ṣẹ̀ Ẹ́. Émọ́sì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Júdà+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí pé wọn kò tẹ̀ lé òfin* Jèhófà Àti nítorí pé wọn kò pa àwọn ìlànà rẹ̀ mọ́;+Irọ́ tí àwọn baba ńlá wọn tọ̀ lẹ́yìn ti mú kí wọ́n ṣìnà.+
11 Gbogbo Ísírẹ́lì ti tẹ Òfin rẹ lójú, wọ́n sì ti yà kúrò nínú rẹ̀ torí pé wọn ò ṣègbọràn sí ohùn rẹ, tí o fi da ègún àti ìbúra lé wa lórí, èyí tí wọ́n kọ sínú Òfin Mósè ìránṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́,+ torí pé a ti ṣẹ̀ Ẹ́.
4 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Júdà+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí pé wọn kò tẹ̀ lé òfin* Jèhófà Àti nítorí pé wọn kò pa àwọn ìlànà rẹ̀ mọ́;+Irọ́ tí àwọn baba ńlá wọn tọ̀ lẹ́yìn ti mú kí wọ́n ṣìnà.+