Émọ́sì 9:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì tó wà ní ìgbèkùn pa dà,+Wọ́n á tún àwọn ìlú tó ti di ahoro kọ́, wọ́n á sì máa gbé inú wọn;+Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n á sì mu wáìnì wọn,+Wọ́n á ṣe ọgbà, wọ́n á sì jẹ èso wọn.’+ Míkà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kálukú wọn máa jókòó* lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀,+Ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló fi ẹnu ara rẹ̀ sọ ọ́.
14 Màá kó àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì tó wà ní ìgbèkùn pa dà,+Wọ́n á tún àwọn ìlú tó ti di ahoro kọ́, wọ́n á sì máa gbé inú wọn;+Wọ́n á gbin ọgbà àjàrà, wọ́n á sì mu wáìnì wọn,+Wọ́n á ṣe ọgbà, wọ́n á sì jẹ èso wọn.’+
4 Kálukú wọn máa jókòó* lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀,+Ẹnì kankan ò sì ní dẹ́rù bà wọ́n,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló fi ẹnu ara rẹ̀ sọ ọ́.