Diutarónómì 32:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ẹ bá àwọn èèyàn+ rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,Torí ó máa gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Ó máa san àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lẹ́san,Ó sì máa ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀.”* Àìsáyà 44:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan! Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀! Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín! Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+
43 Ẹ bá àwọn èèyàn+ rẹ̀ yọ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè,Torí ó máa gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Ó máa san àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lẹ́san,Ó sì máa ṣe ètùtù fún ilẹ̀ àwọn èèyàn rẹ̀.”*
23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan! Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀! Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín! Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+