Jeremáyà 24:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Màá fún wọn ní ọkàn tí á jẹ́ kí wọ́n fẹ́ láti mọ̀ mí, pé èmi ni Jèhófà.+ Wọ́n á di èèyàn mi, màá sì di Ọlọ́run wọn,+ nítorí wọ́n á fi gbogbo ọkàn wọn pa dà sọ́dọ̀ mi.+ Jeremáyà 30:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Ẹ ó di èèyàn mi,+ màá sì di Ọlọ́run yín.”+
7 Màá fún wọn ní ọkàn tí á jẹ́ kí wọ́n fẹ́ láti mọ̀ mí, pé èmi ni Jèhófà.+ Wọ́n á di èèyàn mi, màá sì di Ọlọ́run wọn,+ nítorí wọ́n á fi gbogbo ọkàn wọn pa dà sọ́dọ̀ mi.+