Àìsáyà 47:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Inú bí mi sí àwọn èèyàn mi.+ Mo sọ ogún mi di aláìmọ́,+Mo sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Àmọ́ o ò ṣàánú wọn rárá.+ Kódà, o gbé àjàgà tó wúwo lé àgbàlagbà.+ Jeremáyà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí náà, ìbínú Jèhófà ti kún inú mi,Ara mi ò sì gbà á mọ́.”+ “Dà á sórí ọmọ tó wà lójú ọ̀nà,+Sórí àwọn àwùjọ ọ̀dọ́kùnrin tó kóra jọ. Gbogbo wọn ni ọwọ́ máa tẹ̀, láìyọ ọkùnrin kan àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀,Àwọn àgbàlagbà pẹ̀lú àwọn arúgbó.*+ Ìdárò 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ojú Jèhófà ti fọ́n wọn ká;+Kò ní ṣojú rere sí wọn mọ́. Àwọn èèyàn kò ní bọ̀wọ̀ fún àwọn àlùfáà,+ wọn kò sì ní ṣàánú àwọn àgbààgbà.”+
6 Inú bí mi sí àwọn èèyàn mi.+ Mo sọ ogún mi di aláìmọ́,+Mo sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Àmọ́ o ò ṣàánú wọn rárá.+ Kódà, o gbé àjàgà tó wúwo lé àgbàlagbà.+
11 Torí náà, ìbínú Jèhófà ti kún inú mi,Ara mi ò sì gbà á mọ́.”+ “Dà á sórí ọmọ tó wà lójú ọ̀nà,+Sórí àwọn àwùjọ ọ̀dọ́kùnrin tó kóra jọ. Gbogbo wọn ni ọwọ́ máa tẹ̀, láìyọ ọkùnrin kan àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀,Àwọn àgbàlagbà pẹ̀lú àwọn arúgbó.*+
16 Ojú Jèhófà ti fọ́n wọn ká;+Kò ní ṣojú rere sí wọn mọ́. Àwọn èèyàn kò ní bọ̀wọ̀ fún àwọn àlùfáà,+ wọn kò sì ní ṣàánú àwọn àgbààgbà.”+