-
Diutarónómì 29:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “Tí ìran àwọn ọmọ yín lọ́jọ́ iwájú àti àwọn àjèjì tó wá láti ọ̀nà jíjìn bá rí àwọn àjálù tó bá ilẹ̀ náà, àwọn ìyọnu tí Jèhófà mú wá sórí rẹ̀,
-
-
Diutarónómì 29:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 àwọn àti gbogbo orílẹ̀-èdè máa sọ pé, ‘Kí nìdí tí Jèhófà fi ṣe báyìí sí ilẹ̀ yìí?+ Kí ló fa ìbínú tó le, tó kàmàmà yìí?’
-