-
Nọ́ńbà 28:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “Àmọ́, ní ọjọ́ Sábáàtì,+ kí ọrẹ náà jẹ́ akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méjì tó jẹ́ ọlọ́dún kan tí ara wọn dá ṣáṣá àti ìyẹ̀fun kíkúnná tó jẹ́ ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà tí wọ́n pò mọ́ òróró láti fi ṣe ọrẹ ọkà, pẹ̀lú ọrẹ ohun mímu rẹ̀. 10 Èyí ni ẹbọ sísun ti Sábáàtì, pẹ̀lú ẹbọ sísun ìgbà gbogbo àti ọrẹ+ ohun mímu rẹ̀.
-