-
Sekaráyà 13:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “Ní ọjọ́ yẹn, wọn yóò gbẹ́ kànga kan fún ilé Dáfídì àti fún àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù láti wẹ ẹ̀ṣẹ̀ àti èérí wọn mọ́.+