Ìsíkíẹ́lì 47:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Lẹ́yìn náà, ó mú mi pa dà wá sí ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì náà,+ mo sì rí omi tó ń ṣàn lọ sí ìlà oòrùn láti abẹ́ ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì náà,+ torí iwájú tẹ́ńpìlì náà dojú kọ ìlà oòrùn. Omi náà ń ṣàn wálẹ̀ láti abẹ́ tẹ́ńpìlì náà ní apá ọ̀tún, ní gúúsù pẹpẹ.
47 Lẹ́yìn náà, ó mú mi pa dà wá sí ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì náà,+ mo sì rí omi tó ń ṣàn lọ sí ìlà oòrùn láti abẹ́ ẹnu ọ̀nà tẹ́ńpìlì náà,+ torí iwájú tẹ́ńpìlì náà dojú kọ ìlà oòrùn. Omi náà ń ṣàn wálẹ̀ láti abẹ́ tẹ́ńpìlì náà ní apá ọ̀tún, ní gúúsù pẹpẹ.