Jóòbù 39:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àbí ìwọ lò ń pàṣẹ fún idì, tó fi ń fò lọ sókè,+Tó ń kọ́ ìtẹ́ rẹ̀ síbi tó ga fíofío,+ Jóòbù 39:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Látibẹ̀ ló ti ń wá oúnjẹ;+Ojú rẹ̀ ń ríran jìnnà réré.
27 Àbí ìwọ lò ń pàṣẹ fún idì, tó fi ń fò lọ sókè,+Tó ń kọ́ ìtẹ́ rẹ̀ síbi tó ga fíofío,+ Jóòbù 39:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Látibẹ̀ ló ti ń wá oúnjẹ;+Ojú rẹ̀ ń ríran jìnnà réré.