Léfítíkù 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ ò gbọ́dọ̀ lu ọmọnìkejì yín ní jìbìtì,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jalè.+ Owó iṣẹ́ alágbàṣe ò gbọ́dọ̀ wà lọ́wọ́ yín di àárọ̀ ọjọ́ kejì.+
13 Ẹ ò gbọ́dọ̀ lu ọmọnìkejì yín ní jìbìtì,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jalè.+ Owó iṣẹ́ alágbàṣe ò gbọ́dọ̀ wà lọ́wọ́ yín di àárọ̀ ọjọ́ kejì.+