Sáàmù 34:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jáwọ́ nínú ohun búburú, kí o sì máa ṣe rere;+Máa wá àlàáfíà, kí o sì máa lépa rẹ̀.+ Àìsáyà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ wẹ ara yín, ẹ jẹ́ kí ara yín mọ́;+Ẹ mú ìwà ibi yín kúrò níwájú mi;Ẹ jáwọ́ nínú ìwà burúkú.+