Sáàmù 51:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Dá ọkàn mímọ́ sí inú mi, Ọlọ́run,+Kí o sì fi ẹ̀mí tuntun sí inú mi,+ èyí tó fìdí múlẹ̀. Jeremáyà 32:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Màá fún wọn ní ọkàn kan+ àti ọ̀nà kan kí wọ́n lè máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo, fún ire wọn àti ti àwọn ọmọ wọn lẹ́yìn wọn.+ Ìsíkíẹ́lì 11:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Èmi yóò mú kí ọkàn wọn ṣọ̀kan,*+ màá sì fi ẹ̀mí tuntun sínú wọn;+ màá mú ọkàn òkúta kúrò lára wọn,+ màá sì fún wọn ní ọkàn ẹran,*+ Éfésù 4:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Torí náà, ẹ máa di tuntun nínú agbára tó ń darí ìrònú yín,*+ 24 kí ẹ sì gbé ìwà tuntun wọ̀,+ èyí tí a dá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run nínú òdodo tòótọ́ àti ìdúróṣinṣin.
39 Màá fún wọn ní ọkàn kan+ àti ọ̀nà kan kí wọ́n lè máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo, fún ire wọn àti ti àwọn ọmọ wọn lẹ́yìn wọn.+
19 Èmi yóò mú kí ọkàn wọn ṣọ̀kan,*+ màá sì fi ẹ̀mí tuntun sínú wọn;+ màá mú ọkàn òkúta kúrò lára wọn,+ màá sì fún wọn ní ọkàn ẹran,*+
23 Torí náà, ẹ máa di tuntun nínú agbára tó ń darí ìrònú yín,*+ 24 kí ẹ sì gbé ìwà tuntun wọ̀,+ èyí tí a dá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run nínú òdodo tòótọ́ àti ìdúróṣinṣin.