ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 5:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Nígbà náà, Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibi ààbò, wọ́n* sì pe ibẹ̀ ní Ìlú Dáfídì; Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́lé yí ká orí Òkìtì*+ àti láwọn ibòmíì nínú ìlú.+

  • 2 Kíróníkà 26:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Yàtọ̀ síyẹn, Ùsáyà kọ́ àwọn ilé gogoro+ sí Jerúsálẹ́mù lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ẹnubodè Igun+ àti lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ẹnubodè Àfonífojì+ àti lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ìtì Ògiri, ó sì mú kí wọ́n lágbára.

  • 2 Kíróníkà 32:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Nígbà tí Hẹsikáyà rí i pé Senakérúbù ti dé, tó sì fẹ́ gbéjà ko Jerúsálẹ́mù,

  • 2 Kíróníkà 32:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Yàtọ̀ síyẹn, ó rí i dájú pé òun tún gbogbo ògiri tó wó lulẹ̀ mọ, ó sì kọ́ àwọn ilé gogoro lé e lórí, ó tún mọ ògiri míì síta. Bákan náà, ó ṣàtúnṣe Òkìtì*+ tó wà ní Ìlú Dáfídì, ó sì ṣe ohun ìjà* tó pọ̀ gan-an àti àwọn apata.

  • 2 Kíróníkà 33:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Ọmọ ọdún méjìlá (12) ni Mánásè+ nígbà tó jọba, ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+

  • 2 Kíróníkà 33:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Lẹ́yìn náà, ó mọ ògiri ẹ̀yìn òde sí Ìlú Dáfídì+ lápá ìwọ̀ oòrùn Gíhónì+ ní àfonífojì títí dé Ẹnubodè Ẹja,+ ó mọ ọ́n yí ká dé Ófélì,+ ó sì mú kí ó ga gan-an. Yàtọ̀ síyẹn, ó yan àwọn olórí ọmọ ogun sí gbogbo àwọn ìlú olódi ní Júdà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́