ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 14:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ohun tí o ṣe burú ju ti gbogbo àwọn tó ṣáájú rẹ, o ṣe ọlọ́run míì fún ara rẹ àti àwọn ère onírin* láti mú mi bínú,+ o sì kẹ̀yìn sí mi.+

  • Nehemáyà 9:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 “Àmọ́, wọ́n ya aláìgbọràn, wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọ,+ wọ́n sì kẹ̀yìn sí Òfin rẹ.* Wọ́n pa àwọn wòlíì rẹ tó kìlọ̀ fún wọn láti mú wọn pa dà sọ́dọ̀ rẹ, wọ́n sì hu ìwà àìlọ́wọ̀ tó bùáyà.+

  • Àìsáyà 17:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí o ti gbàgbé Ọlọ́run+ ìgbàlà rẹ;

      O ò rántí Àpáta+ ààbò rẹ.

      Ìdí nìyẹn tí o fi gbin àwọn ohun tó rẹwà,*

      Tí o sì fi ọ̀mùnú àjèjì* gbìn ín.

  • Jeremáyà 2:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Ǹjẹ́ wúńdíá lè gbàgbé ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀,

      Àbí ìyàwó lè gbàgbé ọ̀já ìgbàyà* rẹ̀?

      Síbẹ̀, àwọn èèyàn mi ti gbàgbé mi tipẹ́tipẹ́.+

  • Jeremáyà 13:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ìpín rẹ nìyí, ìpín tí mo wọ̀n fún ọ,” ni Jèhófà wí,

      “Nítorí pé o ti gbàgbé mi,+ o sì ń gba irọ́ gbọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́